Àwọn àbùdá òde tí ọ̀gbààyègbéwọ̀n (matter) ní| Ọjọgbọn Lawrence Adewọle (OAU) & A. A. Fabeku

Lámèétọ́: Olugbenga ỌlabiyiAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayo Àwọn àbùdá òde (physyical characteristics) tí ọ̀gbààyègbéwọ̀n ní ni: (i) Àwọ̀: Àwọ̀ ni ó ń jẹ́ kí á mọ̀ bóyá funfun (white) ni nǹkan kan … Read More