Ẹ̀kọ́ Ẹ̀dá-oníyè (Biology)| Raji Lateef
Lámèétọ́: Taofeeq AdebayọAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayọ Látìgbà láéláé ni àwọn ènìyàn ti máa ń fẹ láti mọ̀ síi nípa àwọn nǹkan tó wà ní àyíkáa wọn, pàápàá àwọn ohun abẹ̀mí. Èyí … Read More
Lámèétọ́: Taofeeq AdebayọAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayọ Látìgbà láéláé ni àwọn ènìyàn ti máa ń fẹ láti mọ̀ síi nípa àwọn nǹkan tó wà ní àyíkáa wọn, pàápàá àwọn ohun abẹ̀mí. Èyí … Read More
Lámèétọ́: Adedoyin AdegbayeAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayo Jẹjẹrẹ (cancer) jẹ́ àrùn tí ó máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí àwọn hóró (cell) kan nínú ara bá tóbi síi láìní ìjánu, tí wọ́n sì … Read More
Lámèétọ́: Taofeeq AdebayoAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayo Hóró ni oun kan tó kéré jùlọ nínú ẹ̀dá oníyè. Òun náà sì ni ìpìlẹ̀ ìṣẹ̀mí ẹ̀dá oníyè. Bákan náà, a lè rí hóró bíi … Read More
Lámèétọ́: Raji LateefAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayọ Ki a tó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ yìí, kí ni ẹ̀jẹ̀? Ẹ̀jẹ̀ jẹ́ àkójọpọ̀ oje ẹ̀jẹ̀ (plasma) àti àwọn hóró (cell) tó ń yíká nínu ara. Bákan … Read More
Lámèétọ́: Adedoyin AdegbayeAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayọ Nínú ìmọ̀ ẹ̀dá oníyè (biology), hóró (cell) ni ẹyọ tó kéré jù tó le dá sẹ̀mí tó sì jẹ́ pé òhun ló pilẹ̀ gbogbo ẹ̀dá … Read More