New Yoruba Words

Selections from Adebayo (in progress), a book that documents emerging scientific vocabulary in Yoruba

English Yorùbá Notes
batteryẹ̀kì agbára
capacitorẹ̀kì àṣẹ
power bankkóló agbára
dataẹ̀gbà
carrotatọ́ka ọ̀nà-ọ̀fun
cucumberapálá
watermelonbàrà olómidídùn
fireworkakuná
copymẹ́dà (mú-ẹ̀dà)
pastetẹ̀dà (tẹ-ẹ̀dà)
copy and pastemẹ́dà-tẹ̀dà (mú-ẹ̀dà tẹ-ẹ̀dà)
photocopyẹ̀dà iwé
foam (soap)ìfofó
bubbleèhó
surfactantgbórisòpinyà (gbe-ori ohun-kan-ṣe-opinya)
QR codeodù FK (Fèsì Kíá)
digitalolóǹkà
digital communicationìbánisọ̀rọ̀ olóǹkà
phenomenonàríyẹ̀wò
hash (#)agàExample: ìràwọ̀ ẹ́ẹ́ta óókan òdo agà = *310#
star (*)ìràwọ̀Example: ìràwọ̀ ẹ́ẹ́ta óókan òdo agà = *310#
Artificial Intelligence (AI)Òye Àtọwọ́dá (OA)
yardọ̀pá
footẹṣẹ̀
mileibùsọ̀
space (astronomy)gbalasa-òfuurufú
space (punctuation)àlàfo
air spaceàlàfo òfuurufú
helicopterbààlúù agbérapá
astronautaringbalasa (arìnrìn-àjò-gbalasa-òfuurufú)
remote controlapàṣẹ òkèèrè
ROVọkọ̀ agbàṣẹ-òkèèrè
electronicabánáṣiṣẹ́
climate(1) ọ̀wọ́ ojú-ọjọ́
(2) tẹ̀léńtẹ̀lé ojú ọjọ́
climate changeà-yípadà ọ̀wọ́ ojú-ọjọ́
weatheringìyòròmọ́gbà (ì-yòrò-mọ́-ìgbà)
mechanical weatheringìyòròmọ́gbà ẹlẹ́kamẹ́ka
(ì-yòrò-mọ́-ìgbà o-ní-ẹ̀ka-mọ́-ẹ̀ka)
mechanicalẹlẹ́kamẹ́ka (o-ní-ẹ̀ka-mọ́-ẹ̀ka)
EarthIlé-Ayé
MercuryGbóńkán
VenusÀgùàlà
MarsṢàngó
JupiterBàbá-Sàlá
SaturnÒòkaáyẹmí
UranusỌ̀pẹ̀bẹ́
NeptuneOlúbùmọ́
PlutoKúrúnbéte
solar systemsàkáání òòrùn
planetayé
inner planetayé inú
outer planetayé òde
exoplanetayé òkèèrè
galaxyagbo iràwọ̀
computefẹ̀rọsírò
computeraṣíròdárà
computationìfẹ̀rọṣírò
computationalafẹ̀rọṣírò
computableaṣeéfẹ̀rọṣírò
computabilityìṣeéfẹ̀rọṣírò
computationallylọ́nà ìfẹ̀rọṣírò
recomputetúnfẹ̀rọṣírò
recomputationìtúnfẹ̀rọṣírò
precomputekọ́fẹ̀rọṣírò
precomputationìkọ́fẹ̀rọṣírò
altitudeọgangan òfuurufú
electronolódì (o-ní-àṣẹ-òdì)
protonolójú (o-ní-àṣẹ-ojú)
neutronaláìláṣẹ
nuclearkókó, alokókó
nuclear bombàdó-olóró alokókó
nuclear medicineìṣègùn alokókó
charge (noun)àṣẹ
nucleuskókó

Ẹ̀kà

English Yorùbá Notes
bit (b)ẹ̀kà (ẹyọ onkà)
byte (B)ẹkajọ (ẹ̀kà méjọ)
Kilobyte (KB)ẹ̀kàrún (ẹkajọ ẹgbẹ̀rún)
Megabyte (MB)ẹ̀kàlẹ́gbẹ̀ (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀)
Gigabyte (GB)ẹkalẹgbeji (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀jì)
Terabyte (TB)ẹkalẹgbẹta (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀ta)
Petabyte (PB)ẹkalẹgbẹrin (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀rin)
Exabyte (EB)ẹkalẹgbarun (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbarun)
Zettabyte (ZB)ẹkalẹgbẹfa (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀fa)
Yottabyte (YB)ẹkalẹgbeje (ẹkajọ ẹgbẹ̀lẹgbeje)

Ọ̀wọ́ alòǹkà (n-ary paradigm)

English Yorùbá Notes
unary alení a-lo-ení
binary alèjì a-lo-èjì
ternary alẹ́ta a-lo-ẹ̀ta
quaternary alẹ́rin a-lo-ẹ̀rin
quinary alárún a-lo-àrún
senary alẹ́fà a-lo-ẹ̀fà
septenary alẹ́je a-lo-ẹ̀je
octonary alẹ́jọ a-lo-ẹ̀jọ
nonary alẹ́sàn-án a-lo-ẹ̀sàn-án
denary alẹ́wá a-lo-ẹ̀wá

Àwọn àwọ̀

English Yorùbá Notes
red pupa
green ewé
orange ọsàn
yellow òfééfèé/ èsúrú
blue aró
violet èṣè (èṣè-àlùkò)
indigo ẹ̀lú
grey ọlọ́yẹ́
cyan arówé (aro ewe)
gold wúrà
silver fàdákà
bronze bàbàganran
burgundy pupadú (pupa dúdú)
purple èsèédú (èsè àlùkò tó dúdú)
white funfun
ash eérú
pink gbúre
black dúdú
magenta puparó (pupa aro)
hush ẹ̀pọ́nrú (ẹpọn-éérú)
amber òfépa (òfééfèé pupa)
peach òfésàn (òfééfèé ọsàn)
brown ẹ̀pọ́nrúsú
velvet àrán
beige sányán
navy aródú (aró-dúdú)

Àwọn òǹkà ńlá (Large number paradigm)

Million

English Yorùbá
one millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ kan
two millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ méjì
three millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́ta
four millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́rin
five millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ márùún
six millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́fà
seven millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ méje
eight millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́jọ
nine millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́sàán
ten millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́wàá
eleven millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mọ́kànla
twelve millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ méjìlá
thirteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́tàlá
fourteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́rìnlá
fifteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́ẹ̀dógún
sixteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́rìndínlógún
seventeen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mẹ́tàdínlógún
eighteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ méjìdínlógún
nineteen millionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mọ́kàndínlógún
twenty millionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀
twenty-one millionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀
twenty-two millionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀

Billion

English Yorùbá
one billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì kan
two billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì méjì
three billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́ta
four billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́rin
five billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì márùún
six billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́fà
seven billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì méje
eight billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́jọ
nine billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́sàán
ten billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́wàá
eleven billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mọ́kànla
twelve billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì méjìlá
thirteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́tàlá
fourteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́rìnlá
fifteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́ẹ̀dógún
sixteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́rìndínlógún
seventeen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mẹ́tàdínlógún
eighteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì méjìdínlógún
nineteen billionẹgbẹ̀lẹ́gbèjì mọ́kàndínlógún
twenty billionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbèjì
twenty-one billionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbèjì
twenty-two billionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbèjì

Trillion

English Yorùbá
one trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta kan
two trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta méjì
three trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́ta
four trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́rin
five trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta márùún
six trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́fà
seven trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta méje
eight trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́jọ
nine trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́sàán
ten trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́wàá
eleven trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mọ́kànla
twelve trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta méjìlá
thirteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́tàlá
fourteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́rìnlá
fifteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́ẹ̀dógún
sixteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́rìndínlógún
seventeen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mẹ́tàdínlógún
eighteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta méjìdínlógún
nineteen trillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta mọ́kàndínlógún
twenty trillionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta
twenty-one trillionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta
twenty-two trillionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ta

Quadrillion

English Yorùbá
one quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin kan
two quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin méjì
three quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́ta
four quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́rin
five quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin márùún
six quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́fà
seven quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin méje
eight quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́jọ
nine quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́sàán
ten quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́wàá
eleven quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mọ́kànla
twelve quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin méjìlá
thirteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́tàlá
fourteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́rìnlá
fifteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́ẹ̀dógún
sixteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́rìndínlógún
seventeen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mẹ́tàdínlógún
eighteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin méjìdínlógún
nineteen quadrillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin mọ́kàndínlógún
twenty quadrillionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin
twenty-one quadrillionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin
twenty-two quadrillionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rin

Quintillion

English Yorùbá
one quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún kan
two quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún méjì
three quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́ta
four quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́rin
five quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún márùún
six quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́fà
seven quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún méje
eight quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́jọ
nine quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́sàán
ten quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́wàá
eleven quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mọ́kànla
twelve quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún méjìlá
thirteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́tàlá
fourteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́rìnlá
fifteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́ẹ̀dógún
sixteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́rìndínlógún
seventeen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mẹ́tàdínlógún
eighteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún méjìdínlógún
nineteen quintillionẹgbẹ̀lẹ́gbàrún mọ́kàndínlógún
twenty quintillionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbàrún
twenty-one quintillionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbàrún
twenty-two quintillionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbàrún

Sextillion

English Yorùbá
one sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà kan
two sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà méjì
three sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́ta
four sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́rin
five sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà márùún
six sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́fà
seven sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà méje
eight sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́jọ
nine sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́sàán
ten sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́wàá
eleven sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mọ́kànla
twelve sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà méjìlá
thirteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́tàlá
fourteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́rìnlá
fifteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́ẹ̀dógún
sixteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́rìndínlógún
seventeen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mẹ́tàdínlógún
eighteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà méjìdínlógún
nineteen sextillionẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà mọ́kàndínlógún
twenty sextillionogún ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà
twenty-one sextillionogún ení ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà
twenty-two sextillionogún èjì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀fà
EnglishYorubaSupporting Data
watermelonbàrà olómidídùnCheck this survey
carrotatọ́ka ọ̀nà-ọ̀funCheck this video
cucumberapáláCheck this video
batteryẹ̀kì agbára
capacitorẹ̀kì àṣẹ
power bankkóló agbára
dataẹ̀gbà
hash (#)agà
star (*)ìràwọ̀
Pín-in ká
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •