Ọ̀rọ̀ ólóòtú

Olóòtú sọ̀rọ̀ lórí àfojúsùn Science in Yoruba

Olóòtú sọ̀rọ̀ lórí àfojúsùn Science in Yoruba

Posted by Science in Yoruba on Sunday, April 9, 2023
Science in Yoruba mentioned in an academic paper

Science in Yoruba, Arojinle, Think Yoruba First, and Yorubaness are mentioned in a recent study by Olajide Salawu on the amazing work being done by our colleagues at Àtẹ́lẹwọ́. The paper was published in the Journal of African Cultural Studies: https://www.tandfonline.com/eprint/GAUNJWPYRQHJEBUUNHHQ/full?target=10.1080/13696815.2023.2267005

Posted by Science in Yoruba on Thursday, November 16, 2023
Ohùn àwọn olólùfẹ́ Science in Yoruba

Ohùn àwọn olólùfẹ́ Science in Yoruba

Posted by Science in Yoruba on Saturday, June 10, 2023
Ìtàn kékeré kan nípa orílẹ̀-èdè Tọ́kì [A short story about Turkey]

Ìtàn kékeré kan nípa orílẹ̀-èdè Tọ́kì [A short story about Turkey]

Posted by Science in Yoruba on Wednesday, April 19, 2023
Solar system prop

At the Chemistry Department, University of Ibadan. The solar system prop in action.

Posted by Science in Yoruba on Thursday, January 24, 2019
Ìfóńjẹsaralóore (Nutrition)

In this short clip from our first week in the classrooms, Jegede Samuel reviews ìfóńjẹsaralóore (nutrition) with one of the classes we are teaching.

Posted by Science in Yoruba on Thursday, January 24, 2019

Taofeeq Adebayo (Doctoral Candidate in Linguistics, Tulane University) ṣe atunyẹwo-ẹkọ nipa itumọ 'Basic Science’ pẹlu awọn ọmọ JSS1 ni Orogun Grammar School, Ibadan. Atunyẹwo-ẹkọ yi waye ni osu kini ọdun 2019.

Posted by Science in Yoruba on Thursday, June 4, 2020

Posted by Science in Yoruba on Friday, June 3, 2022
Science in Yoruba project (2018-2019): sensory organs

Science in Yoruba's Phase 1 Project (2018-2019): sensory organs. Eriifeoluwa Mofoluwawo (MSc, Chemistry, University of Ibadan) ṣe agbeyẹwo itumọ ‘sensory organ’ pẹlu awọn akẹkọ JSS1 ni Orogun Grammar School, Ibadan. Idanilẹkọ yi waye ni osu keji, ọdun 2019.

Posted by Science in Yoruba on Wednesday, February 1, 2023
Samuel Jẹgẹdẹ (MSc Microbiology, University of Ibadan) ṣe afihan 'transformation of energy' fun awọn ọmọ JSS1 ni Orogun Grammar School, Ibadan. Afihan yi waye ni osu keji ọdun 2019.

Samuel Jẹgẹdẹ (MSc Microbiology, University of Ibadan) ṣe afihan 'transformation of energy' fun awọn ọmọ JSS1 ni Orogun Grammar School, Ibadan. Afihan yi waye ni osu keji ọdun 2019.

Posted by Science in Yoruba on Thursday, May 28, 2020
Pín-in ká
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •  
  •