Atakóró wo̩nú wínní-wínní 1| Fààbú sáyẹ́ǹsì láti ọwọ́ Bọ̀dé Ọ̀jẹ̀

Lámèétọ́: Raji LateefAṣàgbéjáde: Taofeeq Adebayo Pè̩lú ìfajúro ni o̩mo̩débìrin kan tí orúko̩ rè̩ ń jé̩ Ìmó̩wùnmí fi délé lọ́sàn-án o̩jó̩ kan láti ilé-è̩kó̩ọ rè̩. Kìí s̩e pé olùkó̩ rè̩ nà … Read More