Ọ̀gbààyègbéwọ̀n (matter) | Samuel Awẹ́lẹ́wà
Kí ni à ń pè ní ọ̀gbààyègbéwọ̀n (matter)? Ohun tí ò gba ààyè tí ó sí gbé ìwọ̀n ni à ń pè ní ọ̀gbààyègbéwọ̀n. Fùn àpẹẹrẹ, bí a bá da … Read More
Kí ni à ń pè ní ọ̀gbààyègbéwọ̀n (matter)? Ohun tí ò gba ààyè tí ó sí gbé ìwọ̀n ni à ń pè ní ọ̀gbààyègbéwọ̀n. Fùn àpẹẹrẹ, bí a bá da … Read More
Ilé ayé (Earth)
Èròjà aláìlábùlà (Pure element)
Ki ni awọn onimọ ijinlẹ n pe ni èròjà alailabula (pure element)?
Ẹ jẹ ka bẹrẹ irinkerindo wa lati inu fasiti UI ni ilu Ibadan. Bi o ba wuwa a le lọ si ilu miran bii Iseyin, Oyo ati bẹẹbẹẹ lọ. Akojọpọ awọn ilu ni o di ohun ti a n pe ni ipinlẹ.